Loading the player...


INFO:
Eyin alfa l'asiwaju esin àwa oba ko nitori ati nri awon oba kan ti won lo n'ganu kale sí Saudi. Alaye ọrọ yi waye nibi owu kuta ramadan lecture 2025 laafin oba Ahmed Adekunle oyelude makama CON Tegbosun lll olowu kuta